Rúùtù 2:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó bi mí pé, ‘Ẹ jọ̀ọ́, ṣé mo lè pèéṣẹ́+ kí n sì kó àwọn ṣírí* ọkà tí àwọn olùkórè bá fi sílẹ̀?’ Ó sì ti ń ṣiṣẹ́ látàárọ̀, kódà ó ṣẹ̀ṣẹ̀ jókòó sí abẹ́ àtíbàbà kó lè sinmi díẹ̀ ni.”
7 Ó bi mí pé, ‘Ẹ jọ̀ọ́, ṣé mo lè pèéṣẹ́+ kí n sì kó àwọn ṣírí* ọkà tí àwọn olùkórè bá fi sílẹ̀?’ Ó sì ti ń ṣiṣẹ́ látàárọ̀, kódà ó ṣẹ̀ṣẹ̀ jókòó sí abẹ́ àtíbàbà kó lè sinmi díẹ̀ ni.”