6 Jèhófà ń kọjá níwájú rẹ̀, ó sì ń kéde pé: “Jèhófà, Jèhófà, Ọlọ́run aláàánú,+ tó ń gba tẹni rò,*+ tí kì í tètè bínú,+ tí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀*+ àti òtítọ́*+ rẹ̀ sì pọ̀ gidigidi,
8 Náómì sọ fún ìyàwó àwọn ọmọ rẹ̀ méjèèjì pé: “Ẹ pa dà, kí kálukú yín lọ sí ilé ìyá rẹ̀. Kí Jèhófà ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí yín+ bí ẹ ṣe ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí àwọn ọkọ yín tó ti kú àti sí èmi náà.