Rúùtù 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Bóásì wá sọ fún Rúùtù pé: “Gbọ́, ọmọ mi. Má lọ pèéṣẹ́ nínú oko míì, má sì lọ sí ibòmíì, tòsí àwọn òṣìṣẹ́ mi obìnrin+ ni kí o máa wà.
8 Bóásì wá sọ fún Rúùtù pé: “Gbọ́, ọmọ mi. Má lọ pèéṣẹ́ nínú oko míì, má sì lọ sí ibòmíì, tòsí àwọn òṣìṣẹ́ mi obìnrin+ ni kí o máa wà.