Rúùtù 1:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Bí Náómì ṣe pa dà láti ilẹ̀ Móábù+ nìyẹn, òun àti Rúùtù ará Móábù, ìyàwó ọmọ rẹ̀. Wọ́n dé sí Bẹ́tílẹ́hẹ́mù ní ìbẹ̀rẹ̀ ìkórè ọkà bálì.+
22 Bí Náómì ṣe pa dà láti ilẹ̀ Móábù+ nìyẹn, òun àti Rúùtù ará Móábù, ìyàwó ọmọ rẹ̀. Wọ́n dé sí Bẹ́tílẹ́hẹ́mù ní ìbẹ̀rẹ̀ ìkórè ọkà bálì.+