Rúùtù 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Náómì ìyá ọkọ rẹ̀ wá sọ fún un pé: “Ọmọ mi, ǹjẹ́ kò yẹ kí n wá ọkọ míì* fún ọ báyìí,+ kí nǹkan lè lọ dáadáa fún ọ?
3 Náómì ìyá ọkọ rẹ̀ wá sọ fún un pé: “Ọmọ mi, ǹjẹ́ kò yẹ kí n wá ọkọ míì* fún ọ báyìí,+ kí nǹkan lè lọ dáadáa fún ọ?