Rúùtù 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Élímélékì* ni orúkọ ọkùnrin náà, Náómì* ni orúkọ ìyàwó rẹ̀, àwọn ọmọ rẹ̀ méjèèjì sì ń jẹ́ Málónì* àti Kílíónì.* Ará Éfúrátà ni wọ́n, ìyẹn Bẹ́tílẹ́hẹ́mù tó wà ní Júdà. Nígbà tí wọ́n dé ilẹ̀ Móábù, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í gbé ibẹ̀.
2 Élímélékì* ni orúkọ ọkùnrin náà, Náómì* ni orúkọ ìyàwó rẹ̀, àwọn ọmọ rẹ̀ méjèèjì sì ń jẹ́ Málónì* àti Kílíónì.* Ará Éfúrátà ni wọ́n, ìyẹn Bẹ́tílẹ́hẹ́mù tó wà ní Júdà. Nígbà tí wọ́n dé ilẹ̀ Móábù, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í gbé ibẹ̀.