Rúùtù 3:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Dúró síbí ní alẹ́ yìí, bó bá tún ọ rà ní àárọ̀ ọ̀la, kò burú! Jẹ́ kó tún ọ rà.+ Àmọ́ bí kò bá fẹ́ tún ọ rà, bí Jèhófà ti ń bẹ, màá tún ọ rà. Torí náà, sùn síbí di àárọ̀.”
13 Dúró síbí ní alẹ́ yìí, bó bá tún ọ rà ní àárọ̀ ọ̀la, kò burú! Jẹ́ kó tún ọ rà.+ Àmọ́ bí kò bá fẹ́ tún ọ rà, bí Jèhófà ti ń bẹ, màá tún ọ rà. Torí náà, sùn síbí di àárọ̀.”