ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 25:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 “Àmọ́ tí ọkùnrin náà kò bá fẹ́ ṣú ìyàwó arákùnrin rẹ̀ lópó, kí ìyàwó arákùnrin rẹ̀ tó kú náà lọ bá àwọn àgbààgbà ní ẹnubodè ìlú, kó sì sọ fún wọn pé, ‘Arákùnrin ọkọ mi kò fẹ́ kí orúkọ arákùnrin rẹ̀ ṣì máa wà ní Ísírẹ́lì. Kò gbà láti ṣú mi lópó.’

  • Diutarónómì 25:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 kí ìyàwó arákùnrin rẹ̀ tó kú náà wá sún mọ́ ọn níṣojú àwọn àgbààgbà, kó bọ́ bàtà ẹsẹ̀ ọkùnrin náà,+ kó tutọ́ sí i lójú, kó sì sọ pé, ‘Ohun tó yẹ kí wọ́n ṣe sí ọkùnrin tí kò fẹ́ kí ìdílé arákùnrin rẹ̀ ṣì máa wà nìyẹn.’

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́