-
1 Sámúẹ́lì 5:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Lẹ́yìn tí wọ́n gbé e dé ibẹ̀, ọwọ́ Jèhófà wá sórí ìlú náà, ó sì kó jìnnìjìnnì bá wọn. Ó fìyà jẹ àwọn èèyàn ìlú náà látorí ẹni kékeré dórí ẹni ńlá, jẹ̀díjẹ̀dí sì kọ lù wọ́n.+
-