-
1 Sámúẹ́lì 6:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Iye àwọn eku wúrà náà jẹ́ iye gbogbo àwọn ìlú Filísínì tí wọ́n jẹ́ ti àwọn alákòóso márààrún, ìyẹn àwọn ìlú olódi àti àwọn abúlé tó wà ní ìgbèríko.
Òkúta ńlá tí wọ́n gbé Àpótí Jèhófà lé sì jẹ́ ẹ̀rí títí di òní yìí ní pápá Jóṣúà ará Bẹti-ṣémẹ́ṣì.
-