-
1 Sámúẹ́lì 6:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ní báyìí, ẹ ṣètò kẹ̀kẹ́ tuntun kan àti abo màlúù méjì tó ní ọmọ, tí a kò ti àjàgà bọ̀ lọ́rùn rí. Kí ẹ wá so àwọn abo màlúù náà mọ́ kẹ̀kẹ́ náà, àmọ́ kí ẹ kó àwọn ọmọ màlúù náà kúrò lọ́dọ̀ wọn pa dà sílé.
-