-
1 Sámúẹ́lì 5:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Nítorí náà, wọ́n ránṣẹ́ pe gbogbo àwọn alákòóso Filísínì jọ, wọ́n bi wọ́n pé: “Kí ni ká ṣe sí Àpótí Ọlọ́run Ísírẹ́lì?” Wọ́n fèsì pé: “Ẹ jẹ́ kí a gbé Àpótí Ọlọ́run Ísírẹ́lì lọ sí Gátì.”+ Torí náà, wọ́n gbé Àpótí Ọlọ́run Ísírẹ́lì lọ síbẹ̀.
-