Àwọn Onídàájọ́ 1:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Nígbà náà, Júdà gba Gásà+ àti agbègbè rẹ̀, Áṣíkẹ́lónì+ àti agbègbè rẹ̀ pẹ̀lú Ẹ́kírónì+ àti agbègbè rẹ̀. 1 Sámúẹ́lì 5:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Nítorí náà, wọ́n gbé Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ ránṣẹ́ sí Ẹ́kírónì,+ àmọ́ gbàrà tí Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ dé Ẹ́kírónì, àwọn ará Ẹ́kírónì bẹ̀rẹ̀ sí í kígbe pé: “Yéè, wọ́n ti gbé Àpótí Ọlọ́run Ísírẹ́lì wá sọ́dọ̀ wa láti pa àwa àti àwọn èèyàn wa!”+
18 Nígbà náà, Júdà gba Gásà+ àti agbègbè rẹ̀, Áṣíkẹ́lónì+ àti agbègbè rẹ̀ pẹ̀lú Ẹ́kírónì+ àti agbègbè rẹ̀.
10 Nítorí náà, wọ́n gbé Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ ránṣẹ́ sí Ẹ́kírónì,+ àmọ́ gbàrà tí Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ dé Ẹ́kírónì, àwọn ará Ẹ́kírónì bẹ̀rẹ̀ sí í kígbe pé: “Yéè, wọ́n ti gbé Àpótí Ọlọ́run Ísírẹ́lì wá sọ́dọ̀ wa láti pa àwa àti àwọn èèyàn wa!”+