Àwọn Onídàájọ́ 10:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Torí náà, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ké pe Jèhófà pé kó ran àwọn lọ́wọ́,+ wọ́n sọ pé: “A ti ṣẹ̀ ọ́, torí a fi Ọlọ́run wa sílẹ̀, a sì ń sin àwọn Báálì.”+
10 Torí náà, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ké pe Jèhófà pé kó ran àwọn lọ́wọ́,+ wọ́n sọ pé: “A ti ṣẹ̀ ọ́, torí a fi Ọlọ́run wa sílẹ̀, a sì ń sin àwọn Báálì.”+