ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 1:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 1 Ọkùnrin kan wà, ó wá láti ìlú Ramataimu-sófíímù*+ ní agbègbè olókè Éfúrémù,+ orúkọ rẹ̀ ni Ẹlikénà,+ ọmọ Jéróhámù, ọmọ Élíhù, ọmọ Tóhù, ọmọ Súfì, ó jẹ́ ará Éfúrémù.

  • 1 Sámúẹ́lì 8:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Nígbà tó yá, gbogbo àgbààgbà Ísírẹ́lì kóra jọ, wọ́n sì wá sọ́dọ̀ Sámúẹ́lì ní Rámà.

  • 1 Sámúẹ́lì 19:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Dáfídì sá àsálà, ó sì sá lọ sọ́dọ̀ Sámúẹ́lì ní Rámà.+ Ó sọ gbogbo ohun tí Sọ́ọ̀lù ti ṣe sí i fún Sámúẹ́lì. Òun àti Sámúẹ́lì bá jáde lọ, wọ́n sì dúró sí Náótì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́