-
1 Sámúẹ́lì 10:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Sámúẹ́lì sọ fún àwọn èèyàn náà nípa ohun tí ọba lẹ́tọ̀ọ́ láti máa gbà lọ́wọ́ wọn,+ ó kọ ọ́ sínú ìwé kan, ó sì fi í lélẹ̀ níwájú Jèhófà. Lẹ́yìn náà, Sámúẹ́lì ní kí gbogbo àwọn èèyàn náà máa lọ, kí kálukú lọ sí ilé rẹ̀.
-