-
2 Àwọn Ọba 1:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Iná ti bọ́ láti ọ̀run, ó sì ti jó àwọn olórí àádọ́ta (50) ọmọ ogun méjì tó ṣáájú run pẹ̀lú àádọ́ta (50) wọn, ṣùgbọ́n ní báyìí, jẹ́ kí ẹ̀mí* mi ṣeyebíye lójú rẹ.”
-