-
2 Kíróníkà 31:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Èyí jẹ́ àfikún sí ohun tí wọ́n pín fún àwọn ọkùnrin láti ọmọ ọdún mẹ́ta sókè tí orúkọ wọn wà nínú àkọsílẹ̀ ìdílé, tí wọ́n ń wá lójoojúmọ́ láti wá ṣe iṣẹ́ ìsìn ní ilé Jèhófà, kí wọ́n sì ṣe iṣẹ́ àwùjọ tí wọ́n pín wọn sí.
-