1 Sámúẹ́lì 14:51 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 51 Kíṣì+ ni bàbá Sọ́ọ̀lù, Nérì+ bàbá Ábínérì sì ni ọmọ Ábíélì. 1 Kíróníkà 8:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Nérì+ bí Kíṣì; Kíṣì bí Sọ́ọ̀lù;+ Sọ́ọ̀lù bí Jónátánì,+ Maliki-ṣúà,+ Ábínádábù+ àti Eṣibáálì.*+ Ìṣe 13:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Àmọ́ nígbà tó yá, wọ́n ní àwọn fẹ́ ọba,+ Ọlọ́run sì fún wọn ní Sọ́ọ̀lù ọmọ Kíṣì, ọkùnrin kan látinú ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì,+ ó fi ogójì (40) ọdún jọba.
21 Àmọ́ nígbà tó yá, wọ́n ní àwọn fẹ́ ọba,+ Ọlọ́run sì fún wọn ní Sọ́ọ̀lù ọmọ Kíṣì, ọkùnrin kan látinú ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì,+ ó fi ogójì (40) ọdún jọba.