1 Sámúẹ́lì 3:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Sámúẹ́lì ń dàgbà sí i, Jèhófà fúnra rẹ̀ wà pẹ̀lú rẹ̀,+ kò sì jẹ́ kí èyíkéyìí nínú gbogbo ọ̀rọ̀ rẹ̀ lọ láìṣẹ.*
19 Sámúẹ́lì ń dàgbà sí i, Jèhófà fúnra rẹ̀ wà pẹ̀lú rẹ̀,+ kò sì jẹ́ kí èyíkéyìí nínú gbogbo ọ̀rọ̀ rẹ̀ lọ láìṣẹ.*