-
1 Sámúẹ́lì 16:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ó fèsì pé: “Àlàáfíà ni. Mo wá rúbọ sí Jèhófà ni. Ẹ ya ara yín sí mímọ́, kí ẹ sì bá mi lọ síbi ẹbọ náà.” Ó wá ya Jésè àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ sí mímọ́, lẹ́yìn náà ó pè wọ́n síbi ẹbọ náà.
-