-
1 Sámúẹ́lì 9:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Nígbà tí àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́* Kíṣì bàbá Sọ́ọ̀lù sọ nù, Kíṣì sọ fún Sọ́ọ̀lù ọmọ rẹ̀ pé: “Jọ̀wọ́, mú ọ̀kan lára àwọn ìránṣẹ́ dání, kí o sì lọ wá àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà.”
-
-
1 Sámúẹ́lì 9:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Sọ́ọ̀lù wá sọ fún ìránṣẹ́ rẹ̀ pé: “Ọ̀rọ̀ rẹ dára. Jẹ́ ká lọ.” Torí náà, wọ́n lọ sí ìlú tí èèyàn Ọlọ́run tòótọ́ náà wà.
-