Ìṣe 13:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Àmọ́ nígbà tó yá, wọ́n ní àwọn fẹ́ ọba,+ Ọlọ́run sì fún wọn ní Sọ́ọ̀lù ọmọ Kíṣì, ọkùnrin kan látinú ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì,+ ó fi ogójì (40) ọdún jọba.
21 Àmọ́ nígbà tó yá, wọ́n ní àwọn fẹ́ ọba,+ Ọlọ́run sì fún wọn ní Sọ́ọ̀lù ọmọ Kíṣì, ọkùnrin kan látinú ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì,+ ó fi ogójì (40) ọdún jọba.