-
Nọ́ńbà 16:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Inú bí Mósè gan-an, ó sì sọ fún Jèhófà pé: “Má bojú wo ọrẹ ọkà wọn. Mi ò gba kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ kankan lọ́wọ́ wọn, mi ò sì ṣe ìkankan nínú wọn léṣe.”+
-