Ẹ́kísódù 3:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wò ó! Mo ti gbọ́ igbe àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, mo sì ti rí bí àwọn ará Íjíbítì ṣe ń fìyà jẹ wọ́n gidigidi.+ 10 Ní báyìí, wá, jẹ́ kí n rán ọ sí Fáráò, wàá sì mú àwọn èèyàn mi, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò ní Íjíbítì.”+
9 Wò ó! Mo ti gbọ́ igbe àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, mo sì ti rí bí àwọn ará Íjíbítì ṣe ń fìyà jẹ wọ́n gidigidi.+ 10 Ní báyìí, wá, jẹ́ kí n rán ọ sí Fáráò, wàá sì mú àwọn èèyàn mi, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò ní Íjíbítì.”+