Àwọn Onídàájọ́ 3:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tún bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe ohun tó burú lójú Jèhófà.+ Torí náà, Jèhófà jẹ́ kí Ẹ́gílónì ọba Móábù+ lágbára lórí Ísírẹ́lì, torí wọ́n ṣe ohun tó burú lójú Jèhófà.
12 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tún bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe ohun tó burú lójú Jèhófà.+ Torí náà, Jèhófà jẹ́ kí Ẹ́gílónì ọba Móábù+ lágbára lórí Ísírẹ́lì, torí wọ́n ṣe ohun tó burú lójú Jèhófà.