-
Àwọn Onídàájọ́ 10:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Àmọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sọ fún Jèhófà pé: “A ti ṣẹ̀. Ohunkóhun tó bá dáa lójú rẹ ni kí o ṣe sí wa. Jọ̀ọ́, ṣáà ti gbà wá sílẹ̀ lónìí.”
-