Diutarónómì 10:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “Ní báyìí, ìwọ Ísírẹ́lì, kí ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ fẹ́ kí o ṣe?+ Kò ju pé: kí o máa bẹ̀rù Jèhófà Ọlọ́run rẹ,+ kí o máa rìn ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀,+ kí o máa nífẹ̀ẹ́ rẹ̀, kí o máa fi gbogbo ọkàn rẹ àti gbogbo ara* rẹ sin Jèhófà Ọlọ́run rẹ,+ Diutarónómì 10:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Òun ni Ẹni tí wàá máa yìn.+ Òun ni Ọlọ́run rẹ, tó ṣe gbogbo ohun àgbàyanu àtàwọn ohun tó ń dẹ́rù bani yìí fún ọ, tí o sì fi ojú ara rẹ rí i.+
12 “Ní báyìí, ìwọ Ísírẹ́lì, kí ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ fẹ́ kí o ṣe?+ Kò ju pé: kí o máa bẹ̀rù Jèhófà Ọlọ́run rẹ,+ kí o máa rìn ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀,+ kí o máa nífẹ̀ẹ́ rẹ̀, kí o máa fi gbogbo ọkàn rẹ àti gbogbo ara* rẹ sin Jèhófà Ọlọ́run rẹ,+
21 Òun ni Ẹni tí wàá máa yìn.+ Òun ni Ọlọ́run rẹ, tó ṣe gbogbo ohun àgbàyanu àtàwọn ohun tó ń dẹ́rù bani yìí fún ọ, tí o sì fi ojú ara rẹ rí i.+