1 Sámúẹ́lì 13:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nígbà náà, Jónátánì bá àwùjọ kan lára àwọn ọmọ ogun Filísínì+ tó wà ní Gébà+ jà, ó ṣẹ́gun wọn, àwọn Filísínì sì gbọ́. Ni Sọ́ọ̀lù bá ní kí wọ́n fun ìwo+ jákèjádò gbogbo ilẹ̀ náà, pé: “Kí gbogbo àwọn Hébérù gbọ́ o!”
3 Nígbà náà, Jónátánì bá àwùjọ kan lára àwọn ọmọ ogun Filísínì+ tó wà ní Gébà+ jà, ó ṣẹ́gun wọn, àwọn Filísínì sì gbọ́. Ni Sọ́ọ̀lù bá ní kí wọ́n fun ìwo+ jákèjádò gbogbo ilẹ̀ náà, pé: “Kí gbogbo àwọn Hébérù gbọ́ o!”