-
1 Sámúẹ́lì 13:2, 3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Sọ́ọ̀lù yan ẹgbẹ̀rún mẹ́ta (3,000) èèyàn látinú Ísírẹ́lì; ẹgbẹ̀rún méjì (2,000) lára wọn wà pẹ̀lú Sọ́ọ̀lù ní Míkímáṣì àti ní agbègbè olókè Bẹ́tẹ́lì, ẹgbẹ̀rún kan (1,000) sì wà pẹ̀lú Jónátánì+ ní Gíbíà+ ti Bẹ́ńjámínì. Ó rán ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn tó ṣẹ́ kù lára àwọn èèyàn náà lọ sí àgọ́ wọn. 3 Nígbà náà, Jónátánì bá àwùjọ kan lára àwọn ọmọ ogun Filísínì+ tó wà ní Gébà+ jà, ó ṣẹ́gun wọn, àwọn Filísínì sì gbọ́. Ni Sọ́ọ̀lù bá ní kí wọ́n fun ìwo+ jákèjádò gbogbo ilẹ̀ náà, pé: “Kí gbogbo àwọn Hébérù gbọ́ o!”
-