-
1 Sámúẹ́lì 14:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Gbogbo àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì tí wọ́n fara pa mọ́+ sí agbègbè olókè Éfúrémù gbọ́ pé àwọn Filísínì ti fẹsẹ̀ fẹ, ni àwọn náà bá bẹ̀rẹ̀ sí í lépa wọn lọ lójú ogun náà.
-