1 Sámúẹ́lì 14:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Àwọn èèyàn náà sì bẹ̀rẹ̀ sí í fi wàdùwàdù kó ẹrù ogun, wọ́n mú àgùntàn àti màlúù àti ọmọ màlúù, wọ́n pa wọ́n lórí ilẹ̀, wọ́n sì ń jẹ ẹran náà tẹ̀jẹ̀tẹ̀jẹ̀.+
32 Àwọn èèyàn náà sì bẹ̀rẹ̀ sí í fi wàdùwàdù kó ẹrù ogun, wọ́n mú àgùntàn àti màlúù àti ọmọ màlúù, wọ́n pa wọ́n lórí ilẹ̀, wọ́n sì ń jẹ ẹran náà tẹ̀jẹ̀tẹ̀jẹ̀.+