1 Sámúẹ́lì 14:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Àmọ́ Jónátánì kò tíì gbọ́ pé bàbá rẹ̀ ti mú kí àwọn èèyàn náà búra,+ ni ó bá na ọ̀pá ọwọ́ rẹ̀ jáde, ó sì ti orí rẹ̀ bọ afárá oyin náà. Nígbà tí ó fi kan ẹnu, ara rẹ̀ mókun.*
27 Àmọ́ Jónátánì kò tíì gbọ́ pé bàbá rẹ̀ ti mú kí àwọn èèyàn náà búra,+ ni ó bá na ọ̀pá ọwọ́ rẹ̀ jáde, ó sì ti orí rẹ̀ bọ afárá oyin náà. Nígbà tí ó fi kan ẹnu, ara rẹ̀ mókun.*