Sáàmù 91:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Torí ó máa pàṣẹ fún àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ nítorí rẹ,+Láti máa ṣọ́ ọ ní gbogbo ọ̀nà rẹ.+ Sáàmù 97:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ẹ̀yin tí ẹ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, ẹ kórìíra ohun tó burú.+ Ó ń ṣọ́ ẹ̀mí* àwọn ẹni ìdúróṣinṣin rẹ̀;+Ó ń gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́* àwọn ẹni burúkú.+ Sáàmù 121:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Kò ní jẹ́ kí ẹsẹ̀ rẹ yọ̀.*+ Ẹni tó ń ṣọ́ ọ kò ní tòògbé láé.
10 Ẹ̀yin tí ẹ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, ẹ kórìíra ohun tó burú.+ Ó ń ṣọ́ ẹ̀mí* àwọn ẹni ìdúróṣinṣin rẹ̀;+Ó ń gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́* àwọn ẹni burúkú.+