1 Sámúẹ́lì 11:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ní ọjọ́ kejì, Sọ́ọ̀lù pín àwọn èèyàn náà sí àwùjọ mẹ́ta, wọ́n lọ sí àárín ibùdó náà ní àkókò ìṣọ́ òwúrọ̀,* wọ́n sì ń pa àwọn ọmọ Ámónì+ títí ọ̀sán fi pọ́n. Àwọn tó yè bọ́ fọ́n ká, tó fi jẹ́ pé kò sí méjì lára wọn tí ó wà pa pọ̀.
11 Ní ọjọ́ kejì, Sọ́ọ̀lù pín àwọn èèyàn náà sí àwùjọ mẹ́ta, wọ́n lọ sí àárín ibùdó náà ní àkókò ìṣọ́ òwúrọ̀,* wọ́n sì ń pa àwọn ọmọ Ámónì+ títí ọ̀sán fi pọ́n. Àwọn tó yè bọ́ fọ́n ká, tó fi jẹ́ pé kò sí méjì lára wọn tí ó wà pa pọ̀.