-
1 Sámúẹ́lì 15:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Àmọ́ Sámúẹ́lì sọ pé: “Bí idà rẹ ṣe mú àwọn obìnrin ṣòfò ọmọ, bẹ́ẹ̀ ni ìyá rẹ á ṣe di ẹni tó ṣòfò ọmọ jù láàárín àwọn obìnrin.” Ni Sámúẹ́lì bá ṣá Ágágì sí wẹ́wẹ́ níwájú Jèhófà ní Gílígálì.+
-