-
1 Sámúẹ́lì 9:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Ni Sọ́ọ̀lù bá dáhùn pé: “Ṣebí ọmọ Bẹ́ńjámínì tó kéré jù nínú àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì ni mí,+ tó sì jẹ́ pé ìdílé mi kò já mọ́ nǹkan kan láàárín gbogbo ìdílé ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì? Torí náà, kí nìdí tí o fi bá mi sọ irú ọ̀rọ̀ yìí?”
-
-
1 Sámúẹ́lì 10:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Torí náà, wọ́n wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà pé:+ “Ṣé ọkùnrin náà ò tíì dé ni?” Jèhófà dáhùn pé: “Òun ló fara pa mọ́ sáàárín ẹrù níbẹ̀ yẹn.”
-