1 Sámúẹ́lì 15:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Títí Sámúẹ́lì fi kú, kò rí Sọ́ọ̀lù mọ́, ńṣe ni Sámúẹ́lì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣọ̀fọ̀ nítorí Sọ́ọ̀lù.+ Ó sì dun Jèhófà* pé ó fi Sọ́ọ̀lù jẹ ọba lórí Ísírẹ́lì.+
35 Títí Sámúẹ́lì fi kú, kò rí Sọ́ọ̀lù mọ́, ńṣe ni Sámúẹ́lì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣọ̀fọ̀ nítorí Sọ́ọ̀lù.+ Ó sì dun Jèhófà* pé ó fi Sọ́ọ̀lù jẹ ọba lórí Ísírẹ́lì.+