1 Sámúẹ́lì 16:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Torí náà, ó ránṣẹ́ pè é, ó sì mú un wọlé. Ọmọ náà pupa, ẹyinjú rẹ̀ mọ́ lóló, ó sì rẹwà gan-an.+ Ni Jèhófà bá sọ pé: “Dìde, fòróró yàn án, torí òun nìyí!”+
12 Torí náà, ó ránṣẹ́ pè é, ó sì mú un wọlé. Ọmọ náà pupa, ẹyinjú rẹ̀ mọ́ lóló, ó sì rẹwà gan-an.+ Ni Jèhófà bá sọ pé: “Dìde, fòróró yàn án, torí òun nìyí!”+