1 Sámúẹ́lì 17:58 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 58 Sọ́ọ̀lù wá sọ fún un pé: “Ọmọ ta ni ọ́, ìwọ ọmọdékùnrin yìí?” Dáfídì fèsì pé: “Ọmọ Jésè + ìránṣẹ́ rẹ ará Bẹ́tílẹ́hẹ́mù ni.”+ Míkà 5:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ìwọ Bẹ́tílẹ́hẹ́mù Éfúrátà,+Ìwọ tó kéré jù láti wà lára àwọn ẹgbẹẹgbẹ̀rún* Júdà,Inú rẹ ni ẹni tí mo fẹ́ kó ṣàkóso Ísírẹ́lì ti máa jáde wá,+Ẹni tó ti wà láti ìgbà àtijọ́, láti àwọn ọjọ́ tó ti pẹ́. Mátíù 2:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 ‘Ìwọ Bẹ́tílẹ́hẹ́mù ti ilẹ̀ Júdà, lọ́nàkọnà, ìwọ kọ́ ni ìlú tó rẹlẹ̀ jù lára àwọn gómìnà Júdà, torí inú rẹ ni alákòóso ti máa jáde wá, ẹni tó máa ṣe olùṣọ́ àgùntàn àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì.’”+
58 Sọ́ọ̀lù wá sọ fún un pé: “Ọmọ ta ni ọ́, ìwọ ọmọdékùnrin yìí?” Dáfídì fèsì pé: “Ọmọ Jésè + ìránṣẹ́ rẹ ará Bẹ́tílẹ́hẹ́mù ni.”+
2 Ìwọ Bẹ́tílẹ́hẹ́mù Éfúrátà,+Ìwọ tó kéré jù láti wà lára àwọn ẹgbẹẹgbẹ̀rún* Júdà,Inú rẹ ni ẹni tí mo fẹ́ kó ṣàkóso Ísírẹ́lì ti máa jáde wá,+Ẹni tó ti wà láti ìgbà àtijọ́, láti àwọn ọjọ́ tó ti pẹ́.
6 ‘Ìwọ Bẹ́tílẹ́hẹ́mù ti ilẹ̀ Júdà, lọ́nàkọnà, ìwọ kọ́ ni ìlú tó rẹlẹ̀ jù lára àwọn gómìnà Júdà, torí inú rẹ ni alákòóso ti máa jáde wá, ẹni tó máa ṣe olùṣọ́ àgùntàn àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì.’”+