1 Kíróníkà 2:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jésè bí àkọ́bí rẹ̀ Élíábù, ìkejì Ábínádábù,+ ìkẹta Ṣíméà,+ 1 Kíróníkà 2:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 ìkẹfà Ósémù àti ìkeje Dáfídì.+