-
Léfítíkù 7:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Tí ẹnikẹ́ni bá jẹ ọ̀rá ẹran tó mú wá láti fi ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà, kí ẹ pa onítọ̀hún kí ẹ lè mú un kúrò láàárín àwọn èèyàn rẹ̀.
-