ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àwọn Onídàájọ́ 20:15, 16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Lọ́jọ́ yẹn, àwọn ọmọ Bẹ́ńjámínì kó ẹgbẹ̀rún mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n (26,000) ọkùnrin tó ń lo idà jọ látinú àwọn ìlú wọn, yàtọ̀ sí ọgọ́rùn-ún méje (700) ọkùnrin tí wọ́n yàn láti Gíbíà. 16 Ọgọ́rùn-ún méje (700) ọkùnrin tí wọ́n yàn tí wọ́n jẹ́ ọlọ́wọ́ òsì wà lára àwọn ọmọ ogun yìí. Gbogbo àwọn ọkùnrin yìí ló lè fi kànnàkànnà ju òkúta ba ìbú fọ́nrán irun, tí kò sì ní tàsé.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́