Jóṣúà 15:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Èyí ni ogún ẹ̀yà Júdà ní ìdílé-ìdílé. Jóṣúà 15:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Ṣááráímù,+ Ádítáímù àti Gédérà pẹ̀lú Gédérótáímù,* gbogbo rẹ̀ jẹ́ ìlú mẹ́rìnlá (14), pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn.
36 Ṣááráímù,+ Ádítáímù àti Gédérà pẹ̀lú Gédérótáímù,* gbogbo rẹ̀ jẹ́ ìlú mẹ́rìnlá (14), pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn.