1 Sámúẹ́lì 1:27, 28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ọmọdékùnrin yìí ni mo gbàdúrà nípa rẹ̀, Jèhófà sì fún mi ní ohun tí mo béèrè lọ́wọ́ rẹ̀.+ 28 Èmi náà sì wá láti fi í fún Jèhófà. Gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀ ló máa fi jẹ́ ti Jèhófà.” Ọkùnrin náà* sì forí balẹ̀ níbẹ̀ fún Jèhófà.
27 Ọmọdékùnrin yìí ni mo gbàdúrà nípa rẹ̀, Jèhófà sì fún mi ní ohun tí mo béèrè lọ́wọ́ rẹ̀.+ 28 Èmi náà sì wá láti fi í fún Jèhófà. Gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀ ló máa fi jẹ́ ti Jèhófà.” Ọkùnrin náà* sì forí balẹ̀ níbẹ̀ fún Jèhófà.