1 Sámúẹ́lì 20:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ni Sọ́ọ̀lù bá ju ọ̀kọ̀ sí i láti fi gún un,+ Jónátánì sì wá mọ̀ pé bàbá òun ti pinnu láti pa Dáfídì.+
33 Ni Sọ́ọ̀lù bá ju ọ̀kọ̀ sí i láti fi gún un,+ Jónátánì sì wá mọ̀ pé bàbá òun ti pinnu láti pa Dáfídì.+