1 Sámúẹ́lì 18:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Dáfídì bẹ̀rẹ̀ sí í jáde lọ, ó sì ń ṣàṣeyọrí*+ níbikíbi tí Sọ́ọ̀lù bá rán an. Torí náà, Sọ́ọ̀lù ní kó máa bójú tó àwọn jagunjagun,+ èyí sì dùn mọ́ gbogbo àwọn èèyàn náà nínú àti àwọn ìránṣẹ́ Sọ́ọ̀lù pẹ̀lú.
5 Dáfídì bẹ̀rẹ̀ sí í jáde lọ, ó sì ń ṣàṣeyọrí*+ níbikíbi tí Sọ́ọ̀lù bá rán an. Torí náà, Sọ́ọ̀lù ní kó máa bójú tó àwọn jagunjagun,+ èyí sì dùn mọ́ gbogbo àwọn èèyàn náà nínú àti àwọn ìránṣẹ́ Sọ́ọ̀lù pẹ̀lú.