1 Sámúẹ́lì 19:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Dáfídì sá àsálà, ó sì sá lọ sọ́dọ̀ Sámúẹ́lì ní Rámà.+ Ó sọ gbogbo ohun tí Sọ́ọ̀lù ti ṣe sí i fún Sámúẹ́lì. Òun àti Sámúẹ́lì bá jáde lọ, wọ́n sì dúró sí Náótì.+
18 Dáfídì sá àsálà, ó sì sá lọ sọ́dọ̀ Sámúẹ́lì ní Rámà.+ Ó sọ gbogbo ohun tí Sọ́ọ̀lù ti ṣe sí i fún Sámúẹ́lì. Òun àti Sámúẹ́lì bá jáde lọ, wọ́n sì dúró sí Náótì.+