-
1 Sámúẹ́lì 10:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Nígbà tí gbogbo àwọn tó mọ̀ ọ́n tẹ́lẹ̀ rí i tó ń sọ tẹ́lẹ̀ pẹ̀lú àwọn wòlíì, wọ́n ń sọ láàárín ara wọn pé: “Kí ló ṣẹlẹ̀ sí ọmọ Kíṣì? Ṣé Sọ́ọ̀lù náà wà lára àwọn wòlíì ni?”
-