-
1 Sámúẹ́lì 19:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Sọ́ọ̀lù fetí sí Jónátánì, Sọ́ọ̀lù sì búra pé: “Bí Jèhófà ti wà láàyè, a ò ní pa á.”
-
-
1 Sámúẹ́lì 19:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Sọ́ọ̀lù fẹ́ fi ọ̀kọ̀ gún Dáfídì mọ́ ògiri, àmọ́ ó yẹ ọ̀kọ̀ Sọ́ọ̀lù, ọ̀kọ̀ náà sì wọnú ògiri. Dáfídì sì sá lọ ní òru ọjọ́ yẹn.
-